Ámósì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta Ísírẹ́lìàní fún mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padàwọ́n ta olódodo fún fàdákààti aláìní fún bàtà ẹsẹ̀ méjèèjì.

Ámósì 2

Ámósì 2:1-10