Àìsáyà 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo bàtà jagunjagun tí a ti lò lójú ogunàti gbogbo ẹ̀wù tí a yí nínú ẹ̀jẹ̀,ni yóò wà fún ìjóná,àti ohun èlò iná dídá.

Àìsáyà 9

Àìsáyà 9:1-8