Àìsáyà 9:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ti sọ orílẹ̀-èdè di ńlá;wọ́n sì yọ̀ níwájúu rẹgẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn ti í yọ ayọ̀ ìkóórè,gẹ́gẹ́ bí ènìyàn ti í yọ̀nígbà tí à ń pín ìkógun.

Àìsáyà 9

Àìsáyà 9:2-4