Àìsáyà 7:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ wàrà tí wọn yóò máa fún un, yóò ní wàràǹkàsì láti jẹ. Gbogbo àwọn tí ó bá kù ní ilẹ̀ náà yóò jẹ wàràǹkàsì àti oyin.

Àìsáyà 7

Àìsáyà 7:20-25