Àìsáyà 7:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo wọn yóò sì wá dó sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè àti pàlàpálá òkúta, lára koríko ẹ̀gún àti gbogbo ibi ihò omi.

Àìsáyà 7

Àìsáyà 7:9-22