Àìsáyà 66:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti oṣù tuntun kan dé òmíràn àti láti ọjọ́ ìsinmi kan dé òmíràn, ni gbogbo ọmọnìyàn yóò wá, wọn yóò sì tẹríba níwájú mi,” ni Olúwa wí.

Àìsáyà 66

Àìsáyà 66:17-24