Àìsáyà 66:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àti Èmi, nítorí ìgbéṣẹ̀ wọn àti èrò wọn, èmi ti múra tán láti wá kó àwọn òrílẹ̀ èdè àti ahọ́n jọ, wọn yóò sì wá wo ògo mi.

Àìsáyà 66

Àìsáyà 66:14-19