Àìsáyà 66:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ bá Jérúsálẹ́mù yọ̀ kí inú yín kí ó sì dùn sí i,gbogbo ẹ̀yin tí ẹ fẹ́ràn rẹ̀;ẹ yọ̀ gidigidi pẹ̀lú rẹ̀,gbogbo ẹ̀yin tí ó ti kẹ́dùn fún un.

Àìsáyà 66

Àìsáyà 66:1-13