Àìsáyà 65:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kì yóò ṣe wàhálà lásántàbí kí wọn bímọ tí ọjọ́ iwájú wọnkì yóò sunwọ̀n;nítorí wọn yóò jẹ́ àwọn ènìyàn ti Olúwa bùkún fún,àwọn àti àwọn ìrandíran wọn pẹ̀lú wọn.

Àìsáyà 65

Àìsáyà 65:13-25