Àìsáyà 65:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yó kọ ilé, wọn yóò sì gbé nínú wọnwọn yóò gbin ọgbà àjàrà, wọn yóò sì jẹ èṣo wọn.

Àìsáyà 65

Àìsáyà 65:11-25