Àìsáyà 65:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò ṣe àjọyọ̀ lórí Jérúsálẹ́mùn ó sì ní inú dídùn nínú àwọn ènìyàn mi;ariwo ẹkún àti igbeni a kì yóò gbọ́ nínú rẹ̀ mọ́,

Àìsáyà 65

Àìsáyà 65:10-20