Àìsáyà 65:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣárónì yóò di pápá oko fún ọ̀wọ́ ẹran,àti àfonífojì Ákò yóò di ibi ìsinmi fún agbo ẹran,fún àwọn ènìyàn mi tí ó wá mi.

Àìsáyà 65

Àìsáyà 65:5-13