Àìsáyà 64:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíbẹ̀ ṣíbẹ̀, Olúwa, ìwọ ni Baba wa.Àwa ni amọ̀, ìwọ ni ọ̀mọ;gbogbo wa jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.

Àìsáyà 64

Àìsáyà 64:1-12