Àìsáyà 64:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn gbogbo nǹkan wọ̀nyí, Olúwa, ìwọó ha sì tún fara rẹ pamọ́ bí?Ìwọ ó ha dákẹ́ kí o sì fìyà jẹwá kọjá ààlà bí?

Àìsáyà 64

Àìsáyà 64:3-12