Àìsáyà 64:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ìbá fa ọ̀run ya kí o sì ṣọ̀kalẹ̀ wá,tí àwọn òkè ńlá yóò fi wárìrì níwájú rẹ!

Àìsáyà 64

Àìsáyà 64:1-7