Àìsáyà 63:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bojúwolẹ̀ láti ọ̀run kí o sì rí iláti ìtẹ́ ògo rẹ, mímọ́ àti ológo.Níbo ni ipá àti agbára rẹ wà?Ìwà jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ rẹ àti àánú rẹ ni atí mú kúrò níwájúu wa.

Àìsáyà 63

Àìsáyà 63:5-19