Àìsáyà 63:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ta ni ó rán ògo apá ti agbára rẹ̀láti wà ní apá ọ̀tún Mósè,ta ni ó pín omi níyà níwájú wọn,láti gba òkìkí ayérayé fún ara rẹ̀,

Àìsáyà 63

Àìsáyà 63:9-14