Àìsáyà 62:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ti fi olùṣọ́ ránṣẹ́ sórí odi rẹ ìwọ Jérúsálẹ́mù;wọn kì yóò lè dákẹ́ tọ̀sán tòru.Ẹ̀yin tí ń ké pe Olúwa,ẹ má ṣe fún ra yín ní ìsinmi,

Àìsáyà 62

Àìsáyà 62:1-12