Àìsáyà 61:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dípò àbùkù wọnàwọn ènìyàn mi yóò gba ìlọ́po-méjì,àti dípò àbùkù wọnwọn yóò yọ̀ nínú ìníi wọn;bẹ́ẹ̀ ni wọn yóò sì jogún ìlọ́po méjì ní ilẹ̀ wọn,ayọ̀ ayérayé yóò sì jẹ́ ti wọn.

Àìsáyà 61

Àìsáyà 61:1-11