Àìsáyà 61:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn àjèjì ni yóò máa da ọ̀wọ́ ẹran rẹ;àwọn àlejò yóò sì ṣiṣẹ́ nínú oko àti ọgbà àjàrà rẹ.

Àìsáyà 61

Àìsáyà 61:1-11