Àìsáyà 60:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ta ni àwọn wọ̀nyí tí ń fò lọ bí i kùrukùru,gẹ́gẹ́ bí àwọn àdàbà sí ìtẹ́ wọn?

Àìsáyà 60

Àìsáyà 60:1-17