Àìsáyà 60:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a ti kóríra rẹ, a sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀,láìsí ẹnìkan tí ó ń gba ọ̀dọ̀ rẹ kọjá,Èmi yóò ṣe ọ́ ní ìṣògo ayérayéàti ayọ̀ àtìrandíran.

Àìsáyà 60

Àìsáyà 60:5-22