Àìsáyà 59:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lódodo ọwọ́ Olúwa kò kúrú láti gbàlà,tàbí kí etí rẹ̀ wúwo láti gbọ́.

Àìsáyà 59

Àìsáyà 59:1-10