Àìsáyà 58:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn rẹ yóò tún ahoro ìṣẹ̀ǹbáyé kọ́wọn yóò sì gbé ìpìlẹ̀ àtijọ́-tijọ́ róa ó sì pè ọ́ ní alátúnṣe ògiri tí ó ti wóàti olùmúbọ̀sípò àwọn òpópónà tí ènìyàn gbé inú un rẹ̀.

Àìsáyà 58

Àìsáyà 58:10-14