Àìsáyà 58:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kígbe rẹ̀ ṣókè, má ṣe fà ṣẹ́yìn.Gbé ohùn rẹ ṣókè bí i ti fèrè.Jẹ́ kí ó di mímọ̀ fún áwọn ènìyàn mi, ọ̀tẹ̀ wọnàti fún ilé Jákọ́bù ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Àìsáyà 58

Àìsáyà 58:1-6