Àìsáyà 57:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin lọ sí Mólẹ́kì pẹ̀lú òróró ólífìẹ sì fi kún òórùn dídùn yín.Ẹ rán ikọ̀ yín lọ jìnnà réré;ẹ sọ̀kalẹ̀ sí ibojì pẹ̀lú!

Àìsáyà 57

Àìsáyà 57:2-17