Àìsáyà 57:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ó fi ń ṣẹlẹ́yà?Ta ni o ń yọ ṣùtì sítí o sì yọ ahọ́n síta?Ẹ̀yin kì í haá ṣe ọlọ̀tẹ̀ ènìyàn bí,àti ìràn àwọn òpùrọ́?

Àìsáyà 57

Àìsáyà 57:1-7