Àìsáyà 57:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ti rí ọ̀nà rẹ̀ gbogbo, ṣùgbọ́n Èmi yóò wò ó sàn;Èmi yóò tọ́ ọ sọ́nà n ó sì mú ìtùnú tọ̀ ọ́ wá,

Àìsáyà 57

Àìsáyà 57:13-21