Àìsáyà 56:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa àwọn ọmọ-ogun sọ wí pé—ẹni tí ó kó àwọn àtìpó Ísírẹ́lì jọ:“Èmi yóò kó àwọn mìíràn jọ pẹ̀lúu wọnyàtọ̀ sí àwọn tí a ti kó jọ.”

Àìsáyà 56

Àìsáyà 56:1-10