Àìsáyà 56:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olùṣọ́ Ísírẹ́lì fọ́jú,gbogbo wọn ṣe aláìní ìmọ̀;Gbogbo wọn jẹ́ adití ajá,wọn kò lè gbó;wọ́n sùn sílẹ̀ wọ́n ń lálàá,wọ́n fẹ́ràn láti máa sùn.

Àìsáyà 56

Àìsáyà 56:4-12