Àìsáyà 55:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gẹ́gẹ́ bí ọ̀run ti ga ju ayé lọ,bẹ́ẹ̀ ni ọ̀nà mi ga ju ọ̀nà yín lọàti èrò mi ju èrò yín lọ.

Àìsáyà 55

Àìsáyà 55:4-13