Àìsáyà 55:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ mi tí ó jáde láti ẹnu mi wá;kì yóò padà sọ́dọ̀ mi lọ́wọ́ òfo,ṣùgbọ́n yóò ṣe ohun tí mo fẹ́,yóò sì mú ète mi tí mo fi rán an wá sí ìmúṣẹ.

Àìsáyà 55

Àìsáyà 55:3-12