Àìsáyà 54:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sí ohun ìjà tí a ṣe sí ọ tí yóò ṣe nǹkan,ìwọ yóò já ahọ́nkáhọ́n tó bá fẹ̀ṣùn kàn ọ́ kulẹ̀.Èyí ni ogún àwọn ìránṣẹ́ Olúwa,èyí sì ni ìdáláre wọn láti ọ̀dọ̀ mi,”ni Olúwa wí.

Àìsáyà 54

Àìsáyà 54:12-17