Àìsáyà 54:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò fi rúbísì ṣe odiì rẹ,àwọn ẹnu ọ̀nà ni a ó fi ohun èlò dáradára fún,àti àwọn ògiri rẹ pẹ̀lú òkúta iyebíye.

Àìsáyà 54

Àìsáyà 54:5-17