Àìsáyà 54:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kọrin, Ìwọ obìnrin àgàn,ìwọ tí kò tí ì bímọ rí;búsí orin, ẹ hó fún ayọ̀,ẹ̀yin tí kò tí ì rọbí rí;nítorí pé púpọ̀ ni ọmọ àwọn obìnrin ìsọdahoroju ti ẹni tí ó ní ọkọ,”ni Olúwa wí.

Àìsáyà 54

Àìsáyà 54:1-7