Àìsáyà 53:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A kẹ́gàn rẹ̀ àwọn ènìyàn sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀,ẹni ìbànújẹ́, tí ó sì mọ bí ìpọ́njú ti rí.Gẹ́gẹ́ bí ẹnìkan tí àwọn ènìyàn ń fojú pamọ́ fúna kẹ́gàn rẹ, a kò sì bọlá fún un rárá.

Àìsáyà 53

Àìsáyà 53:1-4