Àìsáyà 52:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ bú sí orin ayọ̀ papọ̀,ẹ̀yin ahoro Jérúsálẹ́mù,nítorí Olúwa ti tu àwọn ènìyàn rẹ̀ nínú,ó sì ti ra Jérúsálẹ́mù padà.

Àìsáyà 52

Àìsáyà 52:1-15