Àìsáyà 52:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jí, jí, Ìwọ Ṣíhónì,wọ ara rẹ ní agbára.Gbé aṣọ ògo rẹ wọ̀,Ìwọ Jérúsálẹ́mù, ìlú mímọ́ n nì.Àwọn aláìkọlà àti aláìmọ́kì yóò wọ inú un rẹ mọ́.

Àìsáyà 52

Àìsáyà 52:1-6