Àìsáyà 51:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ kọ́ ni ó gbẹ omi òkun bíàti àwọn omi inú ọ̀gbun,Tí o sì ṣe ọ̀nà nínú ìṣàlẹ̀ òkuntó bẹ́ẹ̀ tí àwọn ẹni ìràpadà yóò fi le là á kọjá?

Àìsáyà 51

Àìsáyà 51:6-20