Àìsáyà 49:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ fún mi pé, “Ìránṣẹ́ mi ni ìwọ í ṣe,Ísírẹ́lì nínú ẹni tí n ó ti fi ògo mi hàn.”

Àìsáyà 49

Àìsáyà 49:1-6