Àìsáyà 48:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ a ha ti gbọ́ tàbí ó ti yé ọ bíláti ìgbà àtijọ́ etí kò ti di yíyà.Ǹjẹ́ mo mọ̀ bí o ti jẹ́ alárékérekè tó;a ń pè ọ́ ní ọlọ̀tẹ̀ láti ìgbà ìbí rẹ.

Àìsáyà 48

Àìsáyà 48:2-12