Àìsáyà 48:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sọ àṣọtẹ́lẹ̀ àwọn nǹkan ti tẹ́lẹ̀ lọ́jọ́ tó ti pẹ́,ẹnu mi ló ti kéde wọn, mo sì sọ wọ́n di mímọ̀;Lẹ́yìn náà lójijì mo gbé ìgbéṣẹ̀, wọ́n sì wá sí ìmúṣẹ.

Àìsáyà 48

Àìsáyà 48:1-13