Àìsáyà 48:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ gbárajọ pọ̀ gbogbo yín kí ẹ sì dẹtí:Èwo nínú àwọn ère òrìṣà rẹló ti sọ nǹkan wọ̀nyí?Àkójọpọ̀ àwọn àyànfẹ́ Olúwani yóò gbé ète yìí jáde sí Bábílónì;apá rẹ̀ ni yóò dojú kọ àwọn aráa Bábílónì.

Àìsáyà 48

Àìsáyà 48:4-17