Àìsáyà 46:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lúpẹ̀lú sí àwọn arúgbó àti ewú oríi yínÈmi ni ẹni náà, Èmi ni ẹni tí yóò gbé ọ ró.Èmi ti mọ ọ́, èmi yóò sì gbé ọ;Èmi yóò dì ọ́ mú èmi ó sì gbà ọ́ sílẹ̀.

Àìsáyà 46

Àìsáyà 46:1-9