Àìsáyà 46:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìlà-oòrùn wá ni mo ti pe ẹyẹ ajẹran wá;láti ọ̀nà jíjìn réré, ọkùnrin kan tí yóò mú ète mi ṣẹ.Ohun tí mo ti sọ, òun ni èmi yóò múṣẹ;èyí tí mo ti gbérò, òun ni èmi yóò ṣe.

Àìsáyà 46

Àìsáyà 46:2-13