Àìsáyà 45:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ohun tí Olúwa wí nìyìíẸni Mímọ́ Ísírẹ́lì, àti Ẹlẹ́dàá rẹ̀:Nípa ohun tí ó ń bọ̀,ǹjẹ́ o ń bi mí léèrè nípa àwọn ọmọ mi,tàbí kí o pàṣẹ fún mi nípa iṣẹ́ ọwọ́ mi bí?

Àìsáyà 45

Àìsáyà 45:2-15