Àìsáyà 44:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ohun tí Olúwa wí nìyìíOlùràpadà rẹ tí ó mọ ọ́láti inú ìyá rẹ wá:“Èmi ni Olúwatí ó ti ṣe ohun gbogbotí òun nìkan ti na àwọn ọ̀runtí o sì tẹ́ ayé pẹrẹṣẹ òun tìkálára rẹ̀,

Àìsáyà 44

Àìsáyà 44:14-28