Àìsáyà 44:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Rántí àwọn nǹkan wọ̀nyí, Ìwọ Jákọ́bùnítorí ìránṣẹ́ mi ni ìwọ, Ìwọ Ísírẹ́lì.Èmi ti dá ọ, ìránṣẹ́ mi ni ìwọ ṣe,Èmi Ísírẹ́lì, Èmi kì yóò gbàgbé rẹ.

Àìsáyà 44

Àìsáyà 44:17-24