Àìsáyà 43:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má bẹ̀rù nítorí èmi wà pẹ̀lúù rẹ;Èmi yóò mú àwọn ọmọ rẹ láti ìlà oòrùn wáèmi ó sì kó ọ jọ láti ìwọ̀ oòrùn.

Àìsáyà 43

Àìsáyà 43:4-7