Àìsáyà 43:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi, àní Èmi, Èmi ni ẹni tí ó wẹ àwọnàìṣedédé rẹ nù, nítorí èmi fún ara mi,tí n kò sì rántí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ mọ́.

Àìsáyà 43

Àìsáyà 43:15-27